Rúùtù 4:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bóásì wá lọ sí ẹnubodè ìlú,+ ó sì jókòó síbẹ̀. Sì wò ó, olùtúnrà tí Bóásì sọ̀rọ̀ rẹ̀+ ń kọjá lọ. Ni Bóásì bá sọ pé: “Èèyàn mi,* wá jókòó.” Torí náà, ó yà, ó sì jókòó.
4 Bóásì wá lọ sí ẹnubodè ìlú,+ ó sì jókòó síbẹ̀. Sì wò ó, olùtúnrà tí Bóásì sọ̀rọ̀ rẹ̀+ ń kọjá lọ. Ni Bóásì bá sọ pé: “Èèyàn mi,* wá jókòó.” Torí náà, ó yà, ó sì jókòó.