ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Míkà 7:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 O máa jẹ́ olóòótọ́ sí Jékọ́bù,

      Ìfẹ́ tí o ní sí Ábúráhámù kò ní yẹ̀,

      Bí o ṣe búra fún àwọn baba ńlá wa láti ìgbà àtijọ́.+

  • Lúùkù 1:72, 73
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 72 láti ṣàánú lórí ọ̀rọ̀ àwọn baba ńlá wa, kó sì rántí májẹ̀mú mímọ́ rẹ̀,+ 73 ohun tó búra fún Ábúráhámù baba ńlá wa,+

  • Hébérù 6:13, 14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Torí nígbà tí Ọlọ́run ṣe ìlérí fún Ábúráhámù, ó fi ara rẹ̀ búra, nígbà tó jẹ́ pé kò sí ẹlòmíì tó tóbi jù ú lọ tó lè fi búra,+ 14 ó sọ pé: “Ó dájú pé màá bù kún ọ, ó sì dájú pé màá mú kí o di púpọ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́