Jẹ́nẹ́sísì 12:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ábúrámù mú Sáráì+ ìyàwó rẹ̀ àti Lọ́ọ̀tì ọmọ arákùnrin rẹ̀,+ ó kó gbogbo ẹrù tí wọ́n ti ní+ àti àwọn èèyàn* tó jẹ́ tiwọn ní Háránì, wọ́n sì forí lé ilẹ̀ Kénáánì.+ Nígbà tí wọ́n dé ilẹ̀ Kénáánì,
5 Ábúrámù mú Sáráì+ ìyàwó rẹ̀ àti Lọ́ọ̀tì ọmọ arákùnrin rẹ̀,+ ó kó gbogbo ẹrù tí wọ́n ti ní+ àti àwọn èèyàn* tó jẹ́ tiwọn ní Háránì, wọ́n sì forí lé ilẹ̀ Kénáánì.+ Nígbà tí wọ́n dé ilẹ̀ Kénáánì,