Jẹ́nẹ́sísì 26:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn àkókò díẹ̀, Ábímélékì ọba àwọn Filísínì ń wo ìta látojú fèrèsé,* ó sì rí Ísákì tó ń bá Rèbékà ìyàwó rẹ̀ tage.*+
8 Lẹ́yìn àkókò díẹ̀, Ábímélékì ọba àwọn Filísínì ń wo ìta látojú fèrèsé,* ó sì rí Ísákì tó ń bá Rèbékà ìyàwó rẹ̀ tage.*+