Jẹ́nẹ́sísì 21:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ábúráhámù wá jí ní àárọ̀ kùtù, ó mú búrẹ́dì àti ìgò omi tí wọ́n fi awọ ṣe, ó sì fún Hágárì. Ó gbé e lé èjìká rẹ̀, ó sì ní kí òun àti ọmọ+ náà máa lọ. Hágárì kúrò níbẹ̀, ó sì ń rìn kiri nínú aginjù Bíá-ṣébà.+
14 Ábúráhámù wá jí ní àárọ̀ kùtù, ó mú búrẹ́dì àti ìgò omi tí wọ́n fi awọ ṣe, ó sì fún Hágárì. Ó gbé e lé èjìká rẹ̀, ó sì ní kí òun àti ọmọ+ náà máa lọ. Hágárì kúrò níbẹ̀, ó sì ń rìn kiri nínú aginjù Bíá-ṣébà.+