-
Jẹ́nẹ́sísì 16:7, 8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Nígbà tó yá, áńgẹ́lì Jèhófà rí i níbi ìsun omi kan nínú aginjù, ìsun omi tó wà lójú ọ̀nà Ṣúrì.+ 8 Ó sì sọ pé: “Hágárì, ìránṣẹ́ Sáráì, ibo lo ti ń bọ̀, ibo lo sì ń lọ?” Ó fèsì pé: “Mo sá kúrò lọ́dọ̀ Sáráì ọ̀gá mi ni.”
-