Jẹ́nẹ́sísì 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ọlọ́run sì sọ pé: “Kí àwọn ohun alààyè* máa gbá yìn-ìn nínú omi, kí àwọn ẹ̀dá tó ń fò sì máa fò lójú ọ̀run.”*+
20 Ọlọ́run sì sọ pé: “Kí àwọn ohun alààyè* máa gbá yìn-ìn nínú omi, kí àwọn ẹ̀dá tó ń fò sì máa fò lójú ọ̀run.”*+