Jẹ́nẹ́sísì 36:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Àwọn ọba tó jẹ ní ilẹ̀ Édómù+ nìyí kí ọba kankan tó jẹ lórí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.*+ Nọ́ńbà 20:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Mósè wá ní kí àwọn ìránṣẹ́ lọ láti Kádéṣì sọ́dọ̀ ọba Édómù+ pé: “Ohun tí Ísírẹ́lì+ arákùnrin rẹ sọ nìyí, ‘Gbogbo ìpọ́njú tó dé bá wa ni ìwọ náà mọ̀ dáadáa.
14 Mósè wá ní kí àwọn ìránṣẹ́ lọ láti Kádéṣì sọ́dọ̀ ọba Édómù+ pé: “Ohun tí Ísírẹ́lì+ arákùnrin rẹ sọ nìyí, ‘Gbogbo ìpọ́njú tó dé bá wa ni ìwọ náà mọ̀ dáadáa.