ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 8:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ó fi àwọn àwùjọ ọmọ ogun àdádó sí Édómù. Gbogbo Édómù ni ó fi àwọn àwùjọ ọmọ ogun àdádó sí, gbogbo àwọn ọmọ Édómù sì di ìránṣẹ́ Dáfídì.+ Jèhófà sì ń jẹ́ kí Dáfídì ṣẹ́gun* ní ibikíbi tó bá lọ.+

  • Málákì 1:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Jèhófà sọ pé, “Mo ti fi hàn pé mo nífẹ̀ẹ́ yín.”+

      Àmọ́, ẹ sọ pé: “Kí lo ṣe tó fi hàn pé o nífẹ̀ẹ́ wa?”

      Jèhófà sọ pé, “Ṣebí ọmọ ìyá ni Jékọ́bù àti Ísọ̀?+ Àmọ́ mo nífẹ̀ẹ́ Jékọ́bù, 3 mo sì kórìíra Ísọ̀;+ mo sọ àwọn òkè rẹ̀ di ahoro,+ màá jẹ́ kí àwọn ajáko* inú aginjù gba ogún rẹ̀.”+

  • Róòmù 9:10-13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Kì í ṣe ìgbà yẹn nìkan, àmọ́ ó tún ṣẹlẹ̀ nígbà tí Rèbékà lóyún ìbejì fún ọkùnrin kan, ìyẹn Ísákì baba ńlá wa;+ 11 torí nígbà tí wọn ò tíì bí wọn tàbí tí wọn ò tíì ṣe rere tàbí búburú, kí ìpinnu Ọlọ́run lórí yíyàn má bàa jẹ́ nípa àwọn iṣẹ́, àmọ́ kó jẹ́ nípa Ẹni tó ń peni, 12 a sọ fún un pé: “Ẹ̀gbọ́n ni yóò jẹ́ ẹrú àbúrò.”+ 13 Bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Mo nífẹ̀ẹ́ Jékọ́bù, àmọ́ mo kórìíra Ísọ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́