Jẹ́nẹ́sísì 3:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Jèhófà Ọlọ́run wá sọ pé: “Ọkùnrin náà ti dà bí ọ̀kan lára wa, ó ti mọ rere àti búburú.+ Ní báyìí, kó má bàa na ọwọ́ rẹ̀, kó sì tún mú èso igi ìyè,+ kó jẹ ẹ́, kó sì wà láàyè títí láé,*—”
22 Jèhófà Ọlọ́run wá sọ pé: “Ọkùnrin náà ti dà bí ọ̀kan lára wa, ó ti mọ rere àti búburú.+ Ní báyìí, kó má bàa na ọwọ́ rẹ̀, kó sì tún mú èso igi ìyè,+ kó jẹ ẹ́, kó sì wà láàyè títí láé,*—”