-
Diutarónómì 21:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 lọ́jọ́ tó bá pín ogún fún àwọn ọmọ rẹ̀, kò ní sáyè fún un láti fi ọmọ ìyàwó tó fẹ́ràn ṣe àkọ́bí dípò ọmọ ìyàwó tí kò fẹ́ràn, èyí tó jẹ́ àkọ́bí gangan. 17 Kó gbà pé ọmọ ìyàwó tí òun kò fẹ́ràn ni àkọ́bí, kó fún un ní ìpín méjì nínú gbogbo ohun tó ní, torí òun ni ìbẹ̀rẹ̀ agbára ìbímọ rẹ̀. Òun ló ní ẹ̀tọ́ láti jẹ́ àkọ́bí.+
-