Hébérù 12:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 kí ẹ sì máa kíyè sára, kó má bàa sí ẹnì kankan láàárín yín tó jẹ́ oníṣekúṣe* tàbí ẹnikẹ́ni tí kò mọyì àwọn ohun mímọ́, bí Ísọ̀, tó fi àwọn ẹ̀tọ́ àkọ́bí tó ní tọrẹ nítorí oúnjẹ ẹ̀ẹ̀kan ṣoṣo.+
16 kí ẹ sì máa kíyè sára, kó má bàa sí ẹnì kankan láàárín yín tó jẹ́ oníṣekúṣe* tàbí ẹnikẹ́ni tí kò mọyì àwọn ohun mímọ́, bí Ísọ̀, tó fi àwọn ẹ̀tọ́ àkọ́bí tó ní tọrẹ nítorí oúnjẹ ẹ̀ẹ̀kan ṣoṣo.+