-
Jẹ́nẹ́sísì 24:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ọmọbìnrin náà rẹwà gan-an, wúńdíá ni; ọkùnrin kankan ò bá a lò pọ̀ rí. Ó sọ̀ kalẹ̀ wá síbi ìsun omi náà, ó pọn omi kún ìṣà rẹ̀, ó sì gòkè pa dà.
-