-
Jẹ́nẹ́sísì 21:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Ni Ábúráhámù bá mú àgùntàn àti màlúù, ó kó o fún Ábímélékì, àwọn méjèèjì sì jọ dá májẹ̀mú.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 21:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Ó fèsì pé: “Gba abo ọ̀dọ́ àgùntàn méje náà lọ́wọ́ mi, kó jẹ́ ẹ̀rí pé èmi ni mo gbẹ́ kànga yìí.”
-