Jẹ́nẹ́sísì 17:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ọlọ́run fèsì pé: “Ó dájú pé Sérà ìyàwó rẹ máa bí ọmọkùnrin kan fún ọ, kí o sì sọ ọ́ ní Ísákì.*+ Màá sì fìdí májẹ̀mú mi tí mo bá a dá múlẹ̀, ó máa jẹ́ májẹ̀mú ayérayé fún àtọmọdọ́mọ* rẹ̀.+ Sáàmù 105:9-11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Májẹ̀mú tó bá Ábúráhámù dá+Àti ìbúra rẹ̀ fún Ísákì,+10 Èyí tó gbé kalẹ̀ bí ìlànà fún Jékọ́bùÀti bíi májẹ̀mú tó wà títí láé fún Ísírẹ́lì,11 Ó ní, “Màá fún ọ ní ilẹ̀ Kénáánì+Bí ogún tí a pín fún yín.”+
19 Ọlọ́run fèsì pé: “Ó dájú pé Sérà ìyàwó rẹ máa bí ọmọkùnrin kan fún ọ, kí o sì sọ ọ́ ní Ísákì.*+ Màá sì fìdí májẹ̀mú mi tí mo bá a dá múlẹ̀, ó máa jẹ́ májẹ̀mú ayérayé fún àtọmọdọ́mọ* rẹ̀.+
9 Májẹ̀mú tó bá Ábúráhámù dá+Àti ìbúra rẹ̀ fún Ísákì,+10 Èyí tó gbé kalẹ̀ bí ìlànà fún Jékọ́bùÀti bíi májẹ̀mú tó wà títí láé fún Ísírẹ́lì,11 Ó ní, “Màá fún ọ ní ilẹ̀ Kénáánì+Bí ogún tí a pín fún yín.”+