Jẹ́nẹ́sísì 3:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Jèhófà Ọlọ́run sì fi awọ ṣe aṣọ gígùn fún Ádámù àti ìyàwó rẹ̀ tí wọ́n á máa wọ̀.+