Jẹ́nẹ́sísì 27:11, 12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jékọ́bù sọ fún Rèbékà ìyá rẹ̀ pé: “Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n mi nírun lára,+ àmọ́ èmi ò nírun lára. 12 Tí bàbá mi bá fọwọ́ kàn mí lára+ ńkọ́? Ó dájú pé yóò mọ̀ pé ṣe ni mo tan òun, màá wá mú ègún wá sórí ara mi dípò ìbùkún.”
11 Jékọ́bù sọ fún Rèbékà ìyá rẹ̀ pé: “Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n mi nírun lára,+ àmọ́ èmi ò nírun lára. 12 Tí bàbá mi bá fọwọ́ kàn mí lára+ ńkọ́? Ó dájú pé yóò mọ̀ pé ṣe ni mo tan òun, màá wá mú ègún wá sórí ara mi dípò ìbùkún.”