Jẹ́nẹ́sísì 27:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Kí Ọlọ́run tòótọ́ mú kí ìrì sẹ̀ fún ọ láti ọ̀run,+ kó fún ọ ní àwọn ilẹ̀ tó lọ́ràá ní ayé,+ kó sì fún ọ ní ọkà tó pọ̀ àti wáìnì tuntun.+
28 Kí Ọlọ́run tòótọ́ mú kí ìrì sẹ̀ fún ọ láti ọ̀run,+ kó fún ọ ní àwọn ilẹ̀ tó lọ́ràá ní ayé,+ kó sì fún ọ ní ọkà tó pọ̀ àti wáìnì tuntun.+