Diutarónómì 33:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ísírẹ́lì á máa gbé láìséwu,Orísun Jékọ́bù sì máa wà lọ́tọ̀,Ní ilẹ̀ tí ọkà àti wáìnì tuntun+ wà,Tí ìrì á máa sẹ̀ lójú ọ̀run rẹ̀.+
28 Ísírẹ́lì á máa gbé láìséwu,Orísun Jékọ́bù sì máa wà lọ́tọ̀,Ní ilẹ̀ tí ọkà àti wáìnì tuntun+ wà,Tí ìrì á máa sẹ̀ lójú ọ̀run rẹ̀.+