-
Hébérù 12:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 kí ẹ sì máa kíyè sára, kó má bàa sí ẹnì kankan láàárín yín tó jẹ́ oníṣekúṣe* tàbí ẹnikẹ́ni tí kò mọyì àwọn ohun mímọ́, bí Ísọ̀, tó fi àwọn ẹ̀tọ́ àkọ́bí tó ní tọrẹ nítorí oúnjẹ ẹ̀ẹ̀kan ṣoṣo.+ 17 Torí ẹ mọ̀ pé lẹ́yìn náà, nígbà tó fẹ́ gba ìbùkún náà, a kọ̀ ọ́; torí bó tiẹ̀ sunkún bó ṣe gbìyànjú gan-an láti mú kí èrò yí pa dà,*+ pàbó ló já sí.*
-