Jóṣúà 24:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 mo sì fún Ísákì ní Jékọ́bù àti Ísọ̀.+ Lẹ́yìn náà, mo fún Ísọ̀ ní Òkè Séírì pé kó di tirẹ̀;+ Jékọ́bù àti àwọn ọmọ rẹ̀ sì lọ sí Íjíbítì.+ Hébérù 11:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ìgbàgbọ́ mú kí Ísákì náà súre fún Jékọ́bù+ àti Ísọ̀+ nípa àwọn ohun tó ń bọ̀.
4 mo sì fún Ísákì ní Jékọ́bù àti Ísọ̀.+ Lẹ́yìn náà, mo fún Ísọ̀ ní Òkè Séírì pé kó di tirẹ̀;+ Jékọ́bù àti àwọn ọmọ rẹ̀ sì lọ sí Íjíbítì.+