Jẹ́nẹ́sísì 35:28, 29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ọjọ́ ayé Ísákì sì jẹ́ ọgọ́sàn-án (180) ọdún.+ 29 Ísákì wá mí èémí ìkẹyìn, ó sì kú, wọ́n kó o jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀,* lẹ́yìn tó ti pẹ́ láyé, tí ayé rẹ̀ sì dáa;* Ísọ̀ àti Jékọ́bù ọmọ rẹ̀ sì sin ín.+
28 Ọjọ́ ayé Ísákì sì jẹ́ ọgọ́sàn-án (180) ọdún.+ 29 Ísákì wá mí èémí ìkẹyìn, ó sì kú, wọ́n kó o jọ pẹ̀lú àwọn èèyàn rẹ̀,* lẹ́yìn tó ti pẹ́ láyé, tí ayé rẹ̀ sì dáa;* Ísọ̀ àti Jékọ́bù ọmọ rẹ̀ sì sin ín.+