Ìfihàn 12:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 A wá ju dírágónì ńlá+ náà sísàlẹ̀, ejò àtijọ́ náà,+ ẹni tí à ń pè ní Èṣù+ àti Sátánì,+ tó ń ṣi gbogbo ilẹ̀ ayé tí à ń gbé lọ́nà;+ a jù ú sí ayé,+ a sì ju àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ sísàlẹ̀ pẹ̀lú rẹ̀.
9 A wá ju dírágónì ńlá+ náà sísàlẹ̀, ejò àtijọ́ náà,+ ẹni tí à ń pè ní Èṣù+ àti Sátánì,+ tó ń ṣi gbogbo ilẹ̀ ayé tí à ń gbé lọ́nà;+ a jù ú sí ayé,+ a sì ju àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ sísàlẹ̀ pẹ̀lú rẹ̀.