Ìfihàn 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Lẹ́yìn náà, mo rí àmì ńlá kan ní ọ̀run: Wọ́n fi oòrùn ṣe obìnrin kan+ lọ́ṣọ̀ọ́,* òṣùpá wà lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀, adé oníràwọ̀ méjìlá (12) sì wà ní orí rẹ̀,
12 Lẹ́yìn náà, mo rí àmì ńlá kan ní ọ̀run: Wọ́n fi oòrùn ṣe obìnrin kan+ lọ́ṣọ̀ọ́,* òṣùpá wà lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀, adé oníràwọ̀ méjìlá (12) sì wà ní orí rẹ̀,