Ìfihàn 12:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ogun sì bẹ́ sílẹ̀ ní ọ̀run: Máíkẹ́lì*+ àti àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ bá dírágónì náà jà, dírágónì náà àti àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ sì jà, Ìfihàn 12:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Dírágónì náà wá bínú gidigidi sí obìnrin náà, ó sì lọ bá àwọn tó ṣẹ́ kù lára ọmọ* rẹ̀ jagun,+ àwọn tó ń pa àṣẹ Ọlọ́run mọ́, tí iṣẹ́ wọn sì jẹ́ láti jẹ́rìí Jésù.+
7 Ogun sì bẹ́ sílẹ̀ ní ọ̀run: Máíkẹ́lì*+ àti àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ bá dírágónì náà jà, dírágónì náà àti àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ sì jà,
17 Dírágónì náà wá bínú gidigidi sí obìnrin náà, ó sì lọ bá àwọn tó ṣẹ́ kù lára ọmọ* rẹ̀ jagun,+ àwọn tó ń pa àṣẹ Ọlọ́run mọ́, tí iṣẹ́ wọn sì jẹ́ láti jẹ́rìí Jésù.+