Jẹ́nẹ́sísì 29:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Lábánì tún fún Réṣẹ́lì ọmọ rẹ̀ ní Bílíhà,+ ìránṣẹ́bìnrin rẹ̀ kó lè di ìránṣẹ́+ Réṣẹ́lì.