Ìfihàn 20:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó gbá dírágónì náà+ mú, ejò àtijọ́ náà,+ òun ni Èṣù+ àti Sátánì,+ ó sì dè é fún ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún. Ìfihàn 20:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 A sì ju Èṣù tó ń ṣì wọ́n lọ́nà sínú adágún iná àti imí ọjọ́, níbi tí ẹranko + náà àti wòlíì èké náà wà;+ wọ́n á sì máa joró* tọ̀sántòru títí láé àti láéláé.
2 Ó gbá dírágónì náà+ mú, ejò àtijọ́ náà,+ òun ni Èṣù+ àti Sátánì,+ ó sì dè é fún ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún.
10 A sì ju Èṣù tó ń ṣì wọ́n lọ́nà sínú adágún iná àti imí ọjọ́, níbi tí ẹranko + náà àti wòlíì èké náà wà;+ wọ́n á sì máa joró* tọ̀sántòru títí láé àti láéláé.