Lúùkù 1:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Màríà wá sọ pé: “Ọkàn* mi gbé Jèhófà* ga,+ Lúùkù 1:48 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 48 torí pé ó ti ṣíjú wo ipò tó rẹlẹ̀ tí ẹrúbìnrin rẹ̀ wà.+ Torí, wò ó! láti ìsinsìnyí lọ, gbogbo ìran máa kéde pé aláyọ̀ ni mí,+
48 torí pé ó ti ṣíjú wo ipò tó rẹlẹ̀ tí ẹrúbìnrin rẹ̀ wà.+ Torí, wò ó! láti ìsinsìnyí lọ, gbogbo ìran máa kéde pé aláyọ̀ ni mí,+