Jẹ́nẹ́sísì 29:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Nígbà tí Jèhófà rí i pé Jékọ́bù kò fẹ́ràn* Líà, ó jẹ́ kí Líà lóyún,*+ àmọ́ Réṣẹ́lì yàgàn.+