-
Jẹ́nẹ́sísì 31:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Ní gbogbo ogún (20) ọdún tí mo fi wà pẹ̀lú rẹ, oyún ò bà jẹ́+ lára àwọn àgùntàn rẹ àtàwọn ewúrẹ́ rẹ, mi ò sì jẹ nínú àwọn àgbò rẹ rí.
-