-
Jẹ́nẹ́sísì 30:32Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
32 Màá gba àárín gbogbo agbo ẹran rẹ kọjá lónìí. Kí o ya gbogbo àgùntàn aláwọ̀ tó-tò-tó àtàwọn tó ní oríṣiríṣi àwọ̀ sọ́tọ̀ àti gbogbo àgùntàn tí àwọ̀ rẹ̀ pọ́n rẹ́súrẹ́sú* láàárín àwọn ọmọ àgbò. Kí o sì ya èyíkéyìí tó bá ní oríṣiríṣi àwọ̀ àti àwọ̀ tó-tò-tó sọ́tọ̀ láàárín àwọn abo ewúrẹ́. Láti ìsinsìnyí lọ, àwọn yẹn ló máa jẹ́ èrè mi.+
-