-
Jẹ́nẹ́sísì 30:39Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
39 Torí náà, àwọn ẹran náà máa ń gùn níwájú àwọn ọ̀pá náà, wọ́n sì ń bí àwọn ọmọ tó nílà lára, aláwọ̀ tó-tò-tó àtàwọn tó ní oríṣiríṣi àwọ̀.
-