-
Jẹ́nẹ́sísì 28:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Jékọ́bù wá jí ní àárọ̀ kùtù, ó sì gbé òkúta tó gbórí lé, ó gbé e dúró bí òpó, ó sì da òróró sórí rẹ̀.+
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 28:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Òkúta tí mo gbé kalẹ̀ bí òpó yìí yóò di ilé Ọlọ́run,+ ó sì dájú pé màá fún ọ ní ìdá mẹ́wàá gbogbo ohun tí o fún mi.”
-