Róòmù 8:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Nítorí a tẹ ìṣẹ̀dá lórí ba fún asán,+ kì í ṣe nípa ìfẹ́ òun fúnra rẹ̀, àmọ́ nípasẹ̀ ẹni tó tẹ̀ ẹ́ lórí ba, nítorí ìrètí,
20 Nítorí a tẹ ìṣẹ̀dá lórí ba fún asán,+ kì í ṣe nípa ìfẹ́ òun fúnra rẹ̀, àmọ́ nípasẹ̀ ẹni tó tẹ̀ ẹ́ lórí ba, nítorí ìrètí,