-
Jẹ́nẹ́sísì 31:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Nígbà tó yá, ó gbọ́ ohun tí àwọn ọmọ Lábánì ń sọ pé: “Jékọ́bù ti gba gbogbo ohun tí bàbá wa ní, ó sì ti kó gbogbo ọrọ̀+ yìí jọ látinú àwọn ohun tí bàbá wa ní.”
-