Jẹ́nẹ́sísì 25:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹni ogójì (40) ọdún ni Ísákì nígbà tó fẹ́ Rèbékà, ọmọ Bẹ́túẹ́lì+ ará Arémíà ní ilẹ̀ Padani-árámù, òun ni arábìnrin Lábánì ará Arémíà. Hósíà 12:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jékọ́bù sá lọ sí agbègbè* Árámù;*+Ísírẹ́lì+ ṣiṣẹ́ níbẹ̀ nítorí àtifẹ́ ìyàwó,+Ó sì ń da àgùntàn nítorí ìyàwó.+
20 Ẹni ogójì (40) ọdún ni Ísákì nígbà tó fẹ́ Rèbékà, ọmọ Bẹ́túẹ́lì+ ará Arémíà ní ilẹ̀ Padani-árámù, òun ni arábìnrin Lábánì ará Arémíà.
12 Jékọ́bù sá lọ sí agbègbè* Árámù;*+Ísírẹ́lì+ ṣiṣẹ́ níbẹ̀ nítorí àtifẹ́ ìyàwó,+Ó sì ń da àgùntàn nítorí ìyàwó.+