Sáàmù 105:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ó ní, “Ẹ má fọwọ́ kan àwọn ẹni àmì òróró mi,Ẹ má sì ṣe ohun búburú sí àwọn wòlíì mi.”+