Jẹ́nẹ́sísì 31:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Nígbà tí Lábánì lọ rẹ́ irun àwọn àgùntàn rẹ̀, Réṣẹ́lì jí àwọn ère tẹ́ráfímù*+ tó jẹ́ ti bàbá+ rẹ̀.
19 Nígbà tí Lábánì lọ rẹ́ irun àwọn àgùntàn rẹ̀, Réṣẹ́lì jí àwọn ère tẹ́ráfímù*+ tó jẹ́ ti bàbá+ rẹ̀.