-
Jẹ́nẹ́sísì 31:44, 45Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 Ó yá, jẹ́ ká jọ dá májẹ̀mú, èmi àti ìwọ, ìyẹn ló máa jẹ́ ẹ̀rí láàárín wa.” 45 Jékọ́bù gbé òkúta kan, ó sì gbé e dúró bí òpó.+
-