-
Jẹ́nẹ́sísì 31:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Àmọ́ o ò jẹ́ kí n fi ẹnu ko àwọn ọmọ mi àtàwọn ọmọ ọmọ* mi lẹ́nu. Ìwà òmùgọ̀ lo hù yìí.