Sáàmù 34:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Mo wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà, ó sì dá mi lóhùn.+ Ó gbà mí sílẹ̀ nínú gbogbo ohun tó ń bà mí lẹ́rù.+