1 Àwọn Ọba 12:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Jèróbóámù wá kọ́* Ṣékémù+ ní agbègbè olókè Éfúrémù, ó sì ń gbé ibẹ̀. Láti ibẹ̀, ó lọ kọ́* Pénúélì.+
25 Jèróbóámù wá kọ́* Ṣékémù+ ní agbègbè olókè Éfúrémù, ó sì ń gbé ibẹ̀. Láti ibẹ̀, ó lọ kọ́* Pénúélì.+