Jẹ́nẹ́sísì 32:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Lóru ọjọ́ yẹn, ó dìde, ó mú àwọn ìyàwó rẹ̀ méjèèjì,+ àwọn ìránṣẹ́bìnrin+ rẹ̀ méjèèjì àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ mọ́kànlá (11) tí wọ́n ṣì kéré, wọ́n sì gba ibi tó ṣeé fẹsẹ̀ gbà kọjá nínú odò Jábókù+ sọdá.
22 Lóru ọjọ́ yẹn, ó dìde, ó mú àwọn ìyàwó rẹ̀ méjèèjì,+ àwọn ìránṣẹ́bìnrin+ rẹ̀ méjèèjì àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ mọ́kànlá (11) tí wọ́n ṣì kéré, wọ́n sì gba ibi tó ṣeé fẹsẹ̀ gbà kọjá nínú odò Jábókù+ sọdá.