-
Jẹ́nẹ́sísì 30:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Bílíhà, ìránṣẹ́ Réṣẹ́lì tún lóyún lẹ́ẹ̀kan sí i, nígbà tó yá, ó bí ọmọkùnrin kejì fún Jékọ́bù.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 30:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Lẹ́yìn náà, Sílípà ìránṣẹ́ Líà bí ọmọkùnrin kejì fún Jékọ́bù.
-