-
Jẹ́nẹ́sísì 32:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ó fà wọ́n lé àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ lọ́wọ́, agbo ẹran kan tẹ̀ lé òmíràn, ó sì sọ fún àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ pé: “Ẹ sọdá, kí ẹ máa lọ níwájú mi, kí ẹ sì fi àyè sílẹ̀ láàárín agbo ẹran kan àti èyí tó tẹ̀ lé e.”
-