-
Jẹ́nẹ́sísì 28:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ísọ̀ mọ̀ pé Ísákì ti súre fún Jékọ́bù, ó sì ti ní kó lọ sí Padani-árámù, kó lọ fẹ́ ìyàwó níbẹ̀, ó mọ̀ pé nígbà tó súre fún un, ó pàṣẹ fún un pé: “Má lọ fẹ́ ìyàwó láàárín àwọn ọmọ Kénáánì,”+
-