Jẹ́nẹ́sísì 35:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ fún Jékọ́bù pé: “Gbéra, gòkè lọ sí Bẹ́tẹ́lì,+ ibẹ̀ ni kí o máa gbé, kí o sì mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Ọlọ́run tòótọ́, ẹni tó fara hàn ọ́ nígbà tí ò ń sá fún Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n+ rẹ.” Jẹ́nẹ́sísì 35:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó mọ pẹpẹ kan síbẹ̀, ó sì pe ibẹ̀ ní Eli-bẹ́tẹ́lì,* torí ibẹ̀ ni Ọlọ́run tòótọ́ ti fara hàn án nígbà tó ń sá fún ẹ̀gbọ́n+ rẹ̀.
35 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ fún Jékọ́bù pé: “Gbéra, gòkè lọ sí Bẹ́tẹ́lì,+ ibẹ̀ ni kí o máa gbé, kí o sì mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Ọlọ́run tòótọ́, ẹni tó fara hàn ọ́ nígbà tí ò ń sá fún Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n+ rẹ.”
7 Ó mọ pẹpẹ kan síbẹ̀, ó sì pe ibẹ̀ ní Eli-bẹ́tẹ́lì,* torí ibẹ̀ ni Ọlọ́run tòótọ́ ti fara hàn án nígbà tó ń sá fún ẹ̀gbọ́n+ rẹ̀.