-
Jẹ́nẹ́sísì 30:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Líà tún lóyún lẹ́ẹ̀kan sí i, ó sì bí ọmọkùnrin kẹfà fún Jékọ́bù.+
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 30:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Lẹ́yìn náà, ó bí ọmọbìnrin kan, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Dínà.+
-