Sekaráyà 8:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 “‘Àwọn ohun tó yẹ kí ẹ ṣe nìyí: Ẹ máa bá ara yín sọ òtítọ́,+ kí ẹ sì máa dá ẹjọ́ òtítọ́ àti ti àlàáfíà ní ẹnubodè yín.+
16 “‘Àwọn ohun tó yẹ kí ẹ ṣe nìyí: Ẹ máa bá ara yín sọ òtítọ́,+ kí ẹ sì máa dá ẹjọ́ òtítọ́ àti ti àlàáfíà ní ẹnubodè yín.+