Jẹ́nẹ́sísì 34:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Hámórì sọ fún wọn pé: “Ọkàn Ṣékémù ọmọ mi ń fà sí* ọmọ yín. Ẹ jọ̀ọ́, ẹ fún un kó fi ṣe aya, 9 kí ẹ sì bá wa dána.* Ẹ fún wa ní àwọn ọmọbìnrin yín, kí ẹ̀yin náà sì fẹ́ àwọn ọmọbìnrin wa.+
8 Hámórì sọ fún wọn pé: “Ọkàn Ṣékémù ọmọ mi ń fà sí* ọmọ yín. Ẹ jọ̀ọ́, ẹ fún un kó fi ṣe aya, 9 kí ẹ sì bá wa dána.* Ẹ fún wa ní àwọn ọmọbìnrin yín, kí ẹ̀yin náà sì fẹ́ àwọn ọmọbìnrin wa.+